🌐 Èdè
'Olelo Hawai'iAfaan Oromoobahasa IndonesiaBrezhonegCebuanoChamorroChichewachiShonaChongthuCiyawoDanskDeutschEestiEnglishEspañolEsperantoeʋegbeFrançaisHausaHrvatskiIgboIlocanoItalianoKikuyuKiswahiliKiyombiKreyòl AyisyenLatinaLatviešulietuviųLingálaLugandaMagyarMahasuiMāoriNederlandsNorskPohnpeianPolskiPortuguêsQach’abelRomaniRomânăSetswanaShqipsrpski jezikSuomiSvenskaTagalogTiếng ViệtTonganTwiTürkçeYorùbáÍslenskaČeštinaбеларускаяБългарскиРусскийУкраїнськаעבריתئۇيغۇرچەاردوالعربيةفارسیكوردی سۆرانیअहिराणी‎नेपालीभद्रवाही‎मराठीमानक हिन्दी‎संस्कृत भाषाहरियाणवी‎অসমীয়াবাংলাਪੰਜਾਬੀગુજરાતીଓଡ଼ିଆ‎தமிழ்తెలుగుಕನ್ನಡമലയാളംไทยဗမာἙλληνική中文日本語한국어+ Gbogbo Èdè
See More Jesus
Yorùbá

Kí Ni Bíbélì Wí Nípa Ìṣọ́ra? — Apá Kejì — Ìdánwò Bíbélì

Ìdánwò Bíbélì

Kí Ni Bíbélì Wí Nípa Ìṣọ́ra? — Apá Kejì — Ìdánwò Bíbélì

Fún ìtọ́kasí kọ̀ọ̀kan nísàlẹ̀, yan ohun tí ẹsẹ náà kọ́ni. Ìwọ̀n rẹ yóò farahàn ní ìparí.

Èyí ni àdánwò tí a ń ṣàyẹ̀wò. Kọjá rẹ̀ láti jèrè ẹ̀san sí Ẹ̀rí-ìjẹ́rìí Ìfọwọ́sí Iṣẹ́-Ìsìn rẹ.

2 Peteru 1:10 — Nítorí náà, ará ẹ túbọ̀ máa ṣe àìsimi láti sọ ________ àti yíyàn yín di dájúdájú, nítorí bí ẹ̀yin bá ń ṣe nǹkan wọ̀nyí, ẹ̀yin kì yóò ṣubú.
alẹ́
ìpè
tẹríba
2 Timotiu 2:15 — Ṣaápọn láti fi ara rẹ̀ hàn níwájú Ọlọ́run bi ẹni tí ó yege àti òṣìṣẹ́ tí kò ní láti tijú, tí ó ń ________ ọ̀rọ̀ òtítọ́ bí ó ti yẹ.
dì
jèrè
pín
Òwe 10:4 — Ọwọ́ tí ó lẹ máa ń sọ ènìyàn di tálákà, ṣùgbọ́n ọwọ́ tí ó múra ṣíṣẹ́ a máa sọ ni di ________.
ìmọ̀ràn
ojúrere
ọlọ́rọ̀
Òwe 27:23 — Rí i dájú pé o mọ ipò tí àwọn agbo ________ rẹ wà bojútó àwọn agbo màlúù rẹ dáradára;
òwúrọ̀
ẹnu-ọ̀nà
àgùntàn
Romu 12:8 — Tàbí ẹni tí ó ń gbani níyànjú, sí ìgbìyànjú; ẹni tí ń fi fún ni kí ó máa fi inú kan ṣe é; ẹni tí ń ṣe olórí, kí ó máa ṣe é ní ojú méjèèjì; ẹni tí ń ṣàánú, kí ó máa fi inú ________ ṣe é.
bàtà
ewé
dídùn
Juda 1:3 — Ẹ̀yin ọ̀rẹ́ mi tòótọ́, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé èmí ní ìtara láti kọ̀wé sí i yín nípa ìgbàlà tí í ṣe ti gbogbo ènìyàn, n kò gbọdọ̀ má kọ̀wé sí yín, kí ń sì gbà yín ní ________ láti máa jà fitafita fún ìgbàgbọ́, tí a ti fi lé àwọn ènìyàn mímọ́ lọ́wọ́ ní ẹ̀ẹ̀kan ṣoṣo.
ìfihàn
pípé
ìyànjú
Matiu 7:8 — Nítorí ẹnikẹ́ni tí ó béèrè ń rí gbà, ẹni tí ó bá sì wà kiri ń rí, ẹni bá sì ________ ni a yóò ṣi sílẹ̀ fún.
oníṣègùn
ẹ̀rún
kànkùn
Deuteronomi 4:9 — Kìkì i kí ẹ kíyèsára, kí ẹ sì ṣọ́ra a yín gidigidi kí ẹ má ba à gbàgbé àwọn ohun tí ojú yín ti rí, kí wọn má sì ṣe sá kúrò lóókan ________ yín níwọ̀n ìgbà tí ẹ sì wà láààyè. Ẹ máa fi wọ́n kọ́ àwọn ọmọ yín àti àwọn ọmọ wọn tí ń bọ̀ lẹ́yìn wọn.
àyà
ọkọ
apá
Òwe 4:23 — Ju gbogbo nǹkan tókù lọ, pa ọkàn rẹ mọ́, nítorí òun ni ________ ìyè.
bínú
èrè
orísun
Deuteronomi 6:17 — Ẹ rí i dájú pé ẹ̀ ń pa àwọn òfin Olúwa Ọlọ́run yín mọ́ àti àwọn àṣẹ àti àwọn ________ tí ó ti fún un yín.
ìlànà
ẹ̀yà
àfonífojì
2 Peteru 1:5 — Àti nítorí ìdí èyí, ẹ máa ṣe àìsimi gbogbo, ẹ fi ìwà rere kún ìgbàgbọ́, àti ________ kún ìwà rere;
aginjù
òkúta
ìmọ̀
Heberu 6:11 — Àwa sì fẹ́ kí olúkúlùkù yín máa fi irú àìsimi kan náà hàn, fún ________ ìdánilójú ìrètí títí dé òpin.
ojúlùmọ̀
ìyàtọ̀
ẹ̀kún
Òwe 6:6 — Tọ èèrà lọ, ìwọ ________; kíyèsi ìṣe rẹ̀, kí o sì gbọ́n!
ọlá
ọ̀lẹ
mọ̀
2 Peteru 1:6 — àti àìrékọjá kún ________; àti sùúrù kún àìrékọjá; àti ìwà-bí-Ọlọ́run kún sùúrù.
asán
títí
ìmọ̀

← Padà sí ẹ̀kọ́ náà