🌐 Èdè
'Olelo Hawai'iAfaan Oromoobahasa IndonesiaBrezhonegCebuanoChamorroChichewachiShonaChongthuCiyawoDanskDeutschEestiEnglishEspañolEsperantoeʋegbeFrançaisHausaHrvatskiIgboIlocanoItalianoKikuyuKiswahiliKiyombiKreyòl AyisyenLatinaLatviešulietuviųLingálaLugandaMagyarMahasuiMāoriNederlandsNorskPohnpeianPolskiPortuguêsQach’abelRomaniRomânăSetswanaShqipsrpski jezikSuomiSvenskaTagalogTiếng ViệtTonganTwiTürkçeYorùbáÍslenskaČeštinaбеларускаяБългарскиРусскийУкраїнськаעבריתئۇيغۇرچەاردوالعربيةفارسیكوردی سۆرانیअहिराणी‎नेपालीभद्रवाही‎मराठीमानक हिन्दी‎संस्कृत भाषाहरियाणवी‎অসমীয়াবাংলাਪੰਜਾਬੀગુજરાતીଓଡ଼ିଆ‎தமிழ்తెలుగుಕನ್ನಡമലയാളംไทยဗမာἙλληνική中文日本語한국어+ Gbogbo Èdè
See More Jesus
Yorùbá

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìwà-bí-Ọlọ́run? — Apá 2 — Ìdánwò Bíbélì

Ìdánwò Bíbélì

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìwà-bí-Ọlọ́run? — Apá 2 — Ìdánwò Bíbélì

Fún ìtọ́kasí kọ̀ọ̀kan nísàlẹ̀, yan ohun tí ẹsẹ náà kọ́ni. Ìwọ̀n rẹ yóò farahàn ní ìparí.

Èyí ni àdánwò tí a ń ṣàyẹ̀wò. Kọjá rẹ̀ láti jèrè ẹ̀san sí Ẹ̀rí-ìjẹ́rìí Ìfọwọ́sí Iṣẹ́-Ìsìn rẹ.

Heberu 11:5 — Nípa ìgbàgbọ́ ni a ṣí ________ ní ipò padà kí o má ṣe rí ikú; a kò sì rí i mọ́, nítorí Ọlọ́run ṣí i ní ipò padà ṣáájú ìṣípò padà rẹ̀, a jẹ́rìí yìí sí i pé o wu Ọlọ́run.
Enoku
Titu
Itali
Gẹnẹsisi 17:1 — Ní ìgbà tí ________ di ẹni ọ̀kàndínlọ́gọ́rùn-ún ọdún, Olúwa farahàn án, ó sì wí pé, “Èmi ni Ọlọ́run alágbára, máa rìn níwájú mi, kí o sì jẹ́ aláìlábùkù.
Esau
Abramu
Ṣekemu
2 Timotiu 3:5 — Àwọn tí wọn ní àfarawé ìwà-bí-Ọlọ́run, ṣùgbọ́n tí wọn ________ agbára rẹ̀; yẹra kúrò lọ́dọ̀ àwọn wọ̀nyí pẹ̀lú.
fẹ́
sẹ́
ìjà
2 Peteru 3:13 — Ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí ________ rẹ̀, àwa ń retí àwọn ọ̀run tuntun àti ayé títún nínú èyí tí òdodo ń gbé.
ẹlẹ́rìí
sùn
ìlérí
2 Peteru 1:6 — àti àìrékọjá kún ________; àti sùúrù kún àìrékọjá; àti ìwà-bí-Ọlọ́run kún sùúrù.
asán
títí
ìmọ̀
Oniwaasu 4:12 — Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé, a le è kojú ogun ẹnìkan, àwọn méjì le è gbìjà ara wọn, ìkọ́ okùn mẹ́ta kì í dùn ún ________ fà já.
ìrékọjá
tábìlì
yára
2 Peteru 1:5 — Àti nítorí ìdí èyí, ẹ máa ṣe àìsimi gbogbo, ẹ fi ìwà rere kún ìgbàgbọ́, àti ________ kún ìwà rere;
aginjù
òkúta
ìmọ̀
2 Peteru 1:10 — Nítorí náà, ará ẹ túbọ̀ máa ṣe àìsimi láti sọ ________ àti yíyàn yín di dájúdájú, nítorí bí ẹ̀yin bá ń ṣe nǹkan wọ̀nyí, ẹ̀yin kì yóò ṣubú.
alẹ́
ìpè
tẹríba

← Padà sí ẹ̀kọ́ náà