🌐 Èdè
'Olelo Hawai'iAfaan Oromoobahasa IndonesiaBrezhonegCebuanoChamorroChichewachiShonaChongthuCiyawoDanskDeutschEestiEnglishEspañolEsperantoeʋegbeFrançaisHausaHrvatskiIgboIlocanoItalianoKikuyuKiswahiliKiyombiKreyòl AyisyenLatinaLatviešulietuviųLingálaLugandaMagyarMahasuiMāoriNederlandsNorskPohnpeianPolskiPortuguêsQach’abelRomaniRomânăSetswanaShqipsrpski jezikSuomiSvenskaTagalogTiếng ViệtTonganTwiTürkçeYorùbáÍslenskaČeštinaбеларускаяБългарскиРусскийУкраїнськаעבריתئۇيغۇرچەاردوالعربيةفارسیكوردی سۆرانیअहिराणी‎नेपालीभद्रवाही‎मराठीमानक हिन्दी‎संस्कृत भाषाहरियाणवी‎অসমীয়াবাংলাਪੰਜਾਬੀગુજરાતીଓଡ଼ିଆ‎தமிழ்తెలుగుಕನ್ನಡമലയാളംไทยဗမာἙλληνική中文日本語한국어+ Gbogbo Èdè
See More Jesus
Yorùbá

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Rere Àti Búburú? — Ìpìlẹ̀ — Ìdánwò Bíbélì

Ìdánwò Bíbélì

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Rere Àti Búburú? — Ìpìlẹ̀ — Ìdánwò Bíbélì

Fún ìtọ́kasí kọ̀ọ̀kan nísàlẹ̀, yan ohun tí ẹsẹ náà kọ́ni. Ìwọ̀n rẹ yóò farahàn ní ìparí.

Èyí ni àdánwò tí a ń ṣàyẹ̀wò. Kọjá rẹ̀ láti jèrè ẹ̀san sí Ẹ̀rí-ìjẹ́rìí Ìfọwọ́sí Iṣẹ́-Ìsìn rẹ.

Deuteronomi 30:15 — Wò ó mo gbé kalẹ̀ síwájú u yín lónìí, ìyè àti àlàáfíà, ikú àti ________.
òkùnkùn
ìparun
àìmọ́
Òwe 1:24 — Ṣùgbọ́n ________ bí ẹ ti kọ ìpè ní ìgbà tí mo pè kò sì sí ẹni tí ó kọ ibi ara sí mi gbà tí mo na ọwọ́ sí wọn
níwọ̀n
mọ̀
ọ̀lẹ
Òwe 1:29 — Níwọ́n bí wọ́n ti ________ ìmọ̀ tí wọ́n sì kọ̀ láti bẹ̀rù Olúwa.
kórìíra
pín
kọ́
Jeremiah 13:23 — Ǹjẹ́ Etiopia le yí àwọ̀ rẹ̀ padà? Tàbí ________ lè yí àwọ̀ rẹ̀ padà? Bí èyí kò ti lè rí bẹ́ẹ̀ náà ni ẹ̀yin tí ìwà búburú bá ti mọ́ lára kò lè ṣe rere.
ìkunra
ẹkùn
ìparun
Òwe 4:14 — Má ṣe gbé ẹsẹ̀ rẹ sí ojú ọnà àwọn ènìyàn ________ tàbí kí o rìn ní ọ̀nà àwọn ẹni ibi.
kórìíra
búburú
ìdájọ́
Òwe 4:18 — Ipa ọ̀nà ________ dàbí àṣẹ̀ṣẹ̀yọ oòrùn tí ń tànmọ́lẹ̀ sí i títí ọjọ́ fi kanrí
kórìíra
olódodo
ìmọ̀
Gẹnẹsisi 3:1 — Ejò sá à ṣe ________ ju àwọn ẹranko igbó yòókù tí Olúwa Ọlọ́run dá lọ. Ó sọ fún obìnrin náà pé, “Ǹjẹ́ òtítọ́ ha ni Ọlọ́run wí pé, ‘Ẹ̀yin kò gbọdọ̀ jẹ èso èyíkéyìí lára àwọn igi tí ó wà nínú ọgbà’?”
ìkunra
alárékérekè
eékún
Gẹnẹsisi 3:6 — Nígbà tí obìnrin náà rí i wí pé èso igi náà dára fún oúnjẹ àti pé, ó sì dùn ún wò, àti pé ó ń mú ni ní ọgbọ́n, ó mú díẹ̀ níbẹ̀, ó sì jẹ ẹ́. Ó sì mú díẹ̀ fún ________ rẹ̀, ẹni tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀, òun náà sì jẹ ẹ́.
ipò
ọ̀pá
ọkọ
Gẹnẹsisi 3:22 — Olúwa Ọlọ́run sì wí pé, “Ọkùnrin náà ti dàbí ọ̀kan lára wa, ó mọ rere àti búburú. A kò gbọdọ̀ jẹ́ kí ó na ọwọ́ rẹ̀ kí ó mú lára èso igi ìyè kí ó sì jẹ, kí ó sì wà ________ títí láéláé.”
oúnjẹ
láààyè
sọkún
Gẹnẹsisi 8:20 — ________ sì mọ pẹpẹ fún Olúwa, ó sì mú lára àwọn ẹran tí ó mọ́ àti ẹyẹ tí ó mọ́, ó sì fi rú ẹbọ sísun lórí pẹpẹ.
Ṣela
Tekoa
Noa
Òwe 1:33 — ṣùgbọ́n ________ tí ó bá fetí sí mi, yóò gbé láìléwu yóò sì wà nínú ìdẹ̀ra, láìsí ìbẹ̀rù ìpalára.”
san
ẹnìkan
mọ̀
Òwe 3:13 — ________ ni fún ẹni tí ó ní ìmọ̀, ẹni tí ó tún ní òye sí i
fìtílà
Ìbùkún
ọgbà
Òwe 3:18 — Igi ìyè ni ó jẹ́ fún gbogbo ẹni tí ó bá gbà á; àwọn tí ó bá sì dìímú yóò rí ________ gbà.
ọgbà
ìbùkún
ẹ̀dá
Òwe 4:23 — Ju gbogbo nǹkan tókù lọ, pa ọkàn rẹ mọ́, nítorí òun ni ________ ìyè.
bínú
èrè
orísun
Òwe 8:17 — Mo fẹ́ràn àwọn tí ó fẹ́ràn mi, àwọn tí ó sì ________ mi rí mi.
kọ́
wá
dúró
Isaiah 26:3 — Ìwọ yóò pa á mọ́ ní àlàáfíà ________ ọkàn ẹni tí ó dúró ṣinṣin, nítorí ó gbẹ́kẹ̀lé ọ.
gbẹ̀san
títóbi
pípé
Ìṣe àwọn Aposteli 8:32 — Ibi ìwé mímọ́ tí ________ náà ń kà náà ni èyí: “A fà á bí àgùntàn lọ fún pípa; àti bí ọ̀dọ́-àgùntàn tí ń dákẹ́ níwájú olùrẹ́run rẹ̀, bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni kò wí ohun kan.
ìwẹ̀fà
ajá
àgàbàgebè
Efesu 4:30 — Ẹ má sì ṣe mú Ẹ̀mí Mímọ́ Ọlọ́run bínú, ẹni tí a fi ṣe ________ yín dé ọjọ́ ìdáǹdè.
ìbákasẹ
kúkú
èdìdì

← Padà sí ẹ̀kọ́ náà